Ẹgbẹ agbabọọlu orile-ede Senegal ati Botswana ti ko ẹrù wọn kuro ninu idije bọọlu àwọn obìnrin ni Africa to n lọ lọwọ ni Morocco. Eyi waye lẹyin ti orile-ede Zambia na Senegal ni ami ayo mẹta si meji.
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results